Ẹ̀kọ́ yìí dá lórí í Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè Yorùbá eléyìí tó jẹ́ àkàsọ̀ pàtàkì nínú ẹ̀kọ́ ọ mọ̀-ọ́n kọ mọ̀-ọ́n kà. Bí wọ́n bá bi ọ́ gẹ́gẹ́ bí i akẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá, o gbọ́dọ̀ mọ̀ pé; Lẹ́tà Márùn-úndínlọ́gbọ̀n ló parapọ̀ di Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè Yorùbá. Báwo ló ṣe jẹ́? Ẹ jẹ́ kí á tẹ́tí gbọ́ ọ