News and conversations in colloquial Yoruba

Episode 5: News on Gambian presidential election


Listen Later

This episode focuses on the recently concluded Gambian presidential elections. You would learn some election vocabulary and how to talk about people in Yoruba language. News Transcript:

Nínú ìdìbò orílẹ̀ èdè Gambia, Adama Barrow ni ó mókè. Òun ni ó máa tún darí orílé èdè náà fún ọdún márùn-ún ìmíì. Ìdá métàléláàdóta ìbò ni ó ní, ṣùgbọ́n àwọ̣n àlátakò ẹ̀ sọ pé àwọn ò gba èsì ìbò náà. Oníṣ̣òwò ni Àrẹ Barrow. Ọdún 2017 ni ó kọ́kọ́ díje fún ipò òṣèlú. Ó ṣiṣẹ́ aṣọ́gbà ní Ọdún 2000 ni ̣́UK, nígbà tí ó n lọ sí ilé- ẹ̀kọ́ ní UK. Ó padà sílé ní 2006, ó dẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ìṣòwò ní ọ yẹn. Barrow jẹ́ alátìlẹyìn ẹgbẹ́ agbábọ́lù Arsenal. Ó tún jẹ́ ẹlẹ́sìn mùsùlùmí. Ìyàwó méjì ni Adama Barrow ní. Ó dẹ̀ ní́ ọmọ márùn-ún ṣùgbọ́n ìkan lára àwọn ọmọ ẹ̀ kú ní ọdún 2017 tí ó kọ́kọ́ wọlé sí ipò Àrẹ, lẹ́yìn ti ́ajá gé e jẹ.

...more
View all episodesView all episodes
Download on the App Store

News and conversations in colloquial YorubaBy Mojisola Alawode