Sign up to save your podcasts
Or

Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lu Ààre Yoòbá Dálààsì - Dọ́kítà ṢÍmóǹì Ọlátúnjí
Dokita Simoni Olawale Olatunji ni alase, atokun ati oludari Ile Ise Kojomoonu. Ile Ise ti n k'omo l'ede Yoruba kaakiri gbogbo agbaye. Lori ikanni yi, gbogbo olugbo wa yoo maa je anfani eko ofe ni ede Yoruba. A n k'omo l'asa, orin, iwa, alo, ewa, isesi ati itan ile Yoruba. Oludasile ile ise yi ko fe ki omo kankan ko gbe

Itan n k'omo l'ogbon; itan n k'omo l'ede. Ni aye atiji, itan ni awon baba wa n fii n k'omo ni asa, ewa ati isenbaye ile Yoruba
From the publisher's feed