Yoruba Educational Series

IWA OMOLUWABI ATI BI A SE LE DA OMOLUWABI MO LAWUJO


Listen Later

Koko Ise: 

Iwa Omoluwabi ati bi a se le da Omoluwabi mo lawujo

Omoluwabi ni eni ti o fi iwa bibi ire han yala nipa eko ile tabi iwa ati ise re si enikeji. 


Bi a se le da omoluwabi eniyan mo.Omoluwabi gbodo:

-ni iwa iteriba ati igbowofagba

-ni emi irele

-ni itelorun, omoluwabi kii se ojukokoro. 

-omoluwabi gbodo ko ara re ni ijanu ki o to so tabi se ohunkohun. 

-ni emi igboran 

-je olooto ati olododo

-ni emi suuru

-tepa mose lai se ole

-je eni ti o se gbekele, ti a le fi okan tan ni igba gbogbo.

-omoluwabi kii se ilara tabi jowu enikeji

-ni ife enikeji gege bi ara re.

-ni iwa imototo ni igba gbogbo.

-omoluwabi gbodo jina si awon iwa buburu bii ija, agbeere,  igberaga, imele, ofofo, ole jija, ibinu abbl. 

-gbodo wo aso ti o bo asiri ara nigba gbogbo.

-omoluwabi kii huwa ika

-omoluwabi gbodo pa ogo obinrin mo saaju igbeyawo.

...more
View all episodesView all episodes
Download on the App Store

Yoruba Educational SeriesBy Cecilia

  • 5
  • 5
  • 5
  • 5
  • 5

5

4 ratings