Leta kiko je ona ti a n gba ranse asiri si ara eni. Ninu leta kiko ni a ti maa n ni anfaani julo lati fi ero ara wa han lori ohunkohun. Yala si ore wa, obi wa, ibatan wa, awon oniwe iroyin, oga ile iwe, ijoba, oga ile ise abbl.
Ni kukuru LETA AIGBEFE ni leta ti ko gba efe rara. Eyi ni leta ti a n ko lati wa ise, tabi si ijoba, , ajo gbogbo laarin ilu tabi lawujo tabi nigba ti a ba ni nkan gba lowo awon olu ile ise.
Ewe, a tun le ko irufe leta bayi si
- Olootu iwe iroyin
- Oga ile iwe
- Giwa ile ise abbl.
- Adiresi eni ti o n ko leta
- Deeti
- Ipo ati adiresi eni ti a n ko leta si
- Ikini ibere
- Ori oro/Anole
- Inu leta
-Ikini ipari ati Oruko eni ti o ko leta pelu ifowosi 2 Oluwaseyi Street, Bariga Lagos.
Itoro aye lati lo fun Odun Ibile
Mo fi asiko yi toro aaye lati lo si ilu mi fun ayeye odun egungun ti a maa n se lodoodun.
Inu mi a dun bi e ba le gbami laaaye lati kopa ninu odun yii gege bi asa mi lodoodun.