Sign up to save your podcastsEmail addressPasswordRegisterOrContinue with GoogleAlready have an account? Log in here.
FAQs about Olusam_Babs:How many episodes does Olusam_Babs have?The podcast currently has 22 episodes available.
November 09, 2021TA LÓ NI ÀKÓKÒ RẸ GAN-AN?This talks about owing your time as an individual to enhance a better future....more6minPlay
August 27, 2020Orúkọ Àwọn Ẹyẹ Lédè Gẹ̀ẹ́sì àti Èdè YorùbáẸ̀kọ́ yìí dá lórí í orúkọ tí Ẹ̀yà Yorùbá ń pe Ẹyẹ kọ̀ọ̀kan àti ohun tí à ń pè wọ́n lédè Gẹ̀ẹ́sì....more15minPlay
August 19, 2020Orúkọ Àwọn Ẹranko lédè Gẹ̀ẹ́sì àti YorùbáẸ̀kọ́ yìí wà láti rán àwọn ènìyàn lọ́wọ́ lórí orúkọ ẹranko lédè Gẹ̀ẹ́sì àti Èdè Abínibí wa tí ṣe Yorùbá....more14minPlay
July 05, 2020ÌYÀTỌ̀ ÀṢÀ ÀTI Ẹ̀SÌNỌ̀pọ̀ ènìyàn ló ń fojú ẹ̀sìn wo àṣà, ǹjẹ́ bẹ́ẹ̀ ló rí?...more11minPlay
June 21, 2020Ìró Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè YorùbáA ṣe àgbéyèwò Ìró Fáwẹ̀lì Ède Yorùbá nínú ẹ̀kọ́ yìí............more10minPlay
June 14, 2020Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè YorùbáẸ̀kọ́ yìí dá lórí í Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè Yorùbá eléyìí tó jẹ́ àkàsọ̀ pàtàkì nínú ẹ̀kọ́ ọ mọ̀-ọ́n kọ mọ̀-ọ́n kà. Bí wọ́n bá bi ọ́ gẹ́gẹ́ bí i akẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá, o gbọ́dọ̀ mọ̀ pé; Lẹ́tà Márùn-úndínlọ́gbọ̀n ló parapọ̀ di Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè Yorùbá. Báwo ló ṣe jẹ́? Ẹ jẹ́ kí á tẹ́tí gbọ́ ọ...more15minPlay
FAQs about Olusam_Babs:How many episodes does Olusam_Babs have?The podcast currently has 22 episodes available.