Sign up to save your podcastsEmail addressPasswordRegisterOrContinue with GoogleAlready have an account? Log in here.
The Nigeria Story PodcastThe Nigerian Story Podcast is a show where we discuss issues that have shaped our lives in Nigeria, as well as how Nigerians have influenced events and determine the quality ... more
FAQs about The Nigerian Story Podcast:How many episodes does The Nigerian Story Podcast have?The podcast currently has 73 episodes available.
August 28, 2020Ẹ̀sìn àti Nàìjíríà (2)Ẹ̀sìn àti NàìjíríàẸ kú dédé àsìkò yìí. Ìtàn ọmọ Nàìjíríà la tún mú wá. Ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn kò ṣé fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn. Gbogbo wa la rí bí ètò ẹ̀kọ́, ìlera, àbò àti ẹ̀ka tó kù. Kí wá ni ohun tí ó yẹ kí àwọn adarí ẹ̀sìn wá ṣe láti fi kún ádùrá ni orílẹ̀-èdè wa?Láti gbọ́ ètò tòní ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́...more6minPlay
August 26, 2020Religion and Nigeria (Part 2)It's an indisputable truth that God answers prayers in Nigeria and it's evident in the national miracle of over 4 decades ago?However, today we pray for the progress of our beloved country but the reverse we get. Why? Check out today's podcast as we continue to unravel the mystery behind this......more7minPlay
August 21, 2020ẹ̀sìn àti orílẹ̀-èdè NàìjíríàÈyin olùgbọ wa, a kúu dédé àsìkò yí...Ìtàn ọmọ Nàìjíríà la tún mú tọ̀ yín wá.Lónìí, a ó sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀sìn àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Gbogbo wa la mọ̀ bi ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ṣe pàtàkì ni orílẹ̀-èdè tí a wà yí. Kí ló fàá tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe rí bó ti wà lónì yí pẹ̀lú bí a ti ń ṣe ẹ̀sìn tó? E ó máa gbọ́ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ rẹ̀ lórí ètòo tòní.Ẹ̀bùn gigabyte kan (1000mb) wà fún ẹni tó bá kọ́kọ́ dáhùn ìbéèrè tí ó wà ní ìsàlẹ̀ yí:*Kí ni ẹ̀kọ́ pàtàkì tí a lè rí kọ́ ni ètòo tòní?*E fi ìdáhùn náà ránṣẹ́ sí WhatsApp number yí:+2348133871480...more8minPlay
August 19, 2020Religion and Nigeria (Episode 19)When you see an African man, you see a religious man. The same goes for Nigerians, we don't joke with our religious centres. We attend and organize revivals on every facet of our lives including political and social challenges. But the issue is, most of those political and social challenges remained unsolved.Do you want to know the reason behind that? Well, follow us on today's episode... You can send your comments to Ayodeji on Whatsapp +2348133871480...more7minPlay
August 14, 2020ìtàn àwọn ọmọ Obìnrin Aba (Apa kẹta)Ìtàn ọmọ Nàìjíríà la tún gbédé. Loni laó parí ìtàn àwọn ọmọ Obìnrin Aba (Apa kẹta). Kíni ó ṣẹlẹ̀ ni ìpàdé láàrín àwọn obìnrin yìí ati Aṣojú ìjọba amúnisìn? E ó máa gbọ nínú ètò tòní....more6minPlay
August 12, 2020Aba Women's Riot of 1929 (Part 3)Woah🌹It's another Wednesday.Today's episode is going to wrap-up our story on the Aba Woman's Riot of 1929.Join me as we discuss great women that altered the course of history.Hint: we will be giving out 2G to 2 winners at the end of the show.Please be reminded to listen to previous episodes (English/Yoruba) and share our link with your friends and families😘 (https://anchor.fm/thenigerianstorypodcast) Thank you🌹....more7minPlay
August 07, 2020Rògbòdìyàn àwọn ọmọ obìnrin Àbá (2)Ẹ káàbọ̀ sórí ètò wa. Ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá, a bẹ̀rẹ̀ ẹ ìtàn Rògbòdìyàn àwọn ọmọ obìnrin Àbá ti ọdún 1929. Ìtàn náà ń tẹ̀síwájú lọ́sẹ̀ yí....more10minPlay
August 05, 2020Aba Women's Riot of 1929 Pt 2 (Episode 17)Hey dear, I hope you are enjoying your day? Today, we will continue learning from history by looking at the topic: The Aba Women's Riot of 1929 (Part 2).Please share the link with your friends and family.For more information, contact Ayodeji: +2348133871480...more9minPlay
July 31, 2020Rògbòdìyàn àwọn ọmọ obìnrin ÀbáA kú ọdún oooo.Ìtàn ọmọ Nàìjíríà la tún wá sétí i ìgbọ́ yín. Lọ́sẹ̀ yí, a ó máa sọ̀rọ̀ lórí ìṣẹ̀lẹ̀ ọdún 1929- Rògbòdìyàn àwọn ọmọ obìnrin Àbá (Aba women's Riot). E kú ìtẹ́sílẹ̀....more10minPlay
July 29, 2020Aba Women's Riot of 1929You are welcome back to The Nigeria Story Podcast today.Join us in this interesting episode. we will learn from the past and suggest a way forward for the future.Share and send your comments to Ayodeji Adegbola on WhatsApp +2348133871480 ...more9minPlay
FAQs about The Nigerian Story Podcast:How many episodes does The Nigerian Story Podcast have?The podcast currently has 73 episodes available.